ile-ounjẹ
Appearance
Yoruba
[edit]Etymology
[edit]ilé (“place”) + oúnjẹ (“food”).
Pronunciation
[edit]Noun
[edit]ilé-oúnjẹ
- restaurant
- Mo lọ sí ilé-oúnjẹ Ṣáìnà pẹ̀lú àbúrò mi.
- I went to a Chinese restaurant with my younger sibling.
- dining room
- Synonym: ilé-ìjẹun
- Wọ́n fi í sórí tábìlì ilé-oúnjẹ.
- They put it on the dining room table.