1= orí, orúwo, orígho 2= ojú 3= ọrùn 4= èjìká 5= àyà 6= idodo, ìwọ́ 7= ikùn, ukù 8= ìbàdí 9= okó 10–14= ẹsẹ̀ 10= itan, 11= orúnkún, eékún, ụkọkọ 12= ojúgun, àgbákòrójú 13= ọrùn-ẹsẹ̀, ọ̀gụ̀nrụ̀n-ẹsẹ̀ 14= ẹsẹ̀, ẹ̀tụ̀pá 15–19= apá, aká 16= ìgúnpá, ùgóká, ukókó-uká 18= ọrùn-ọwọ́, ọ̀gụ̀nrụ̀n ọọ́ 19= ọwọ́, ọọ́