ẹri
Appearance
See also: Appendix:Variations of "eri"
Yoruba
[edit]Alternative forms
[edit]Etymology 1
[edit]Pronunciation
[edit]Noun
[edit]ẹri
Derived terms
[edit]Etymology 2
[edit]From ẹ̀- (“nominalizing prefix”) + rí (“to see”).
Alternative forms
[edit]Pronunciation
[edit]Noun
[edit]ẹ̀rí
- evidence, proof, testimony, confirmation, data
- confidence, assurance
- mo jẹ́rìí ọmọ náà ― I am confident in the child
Derived terms
[edit]- Ẹlẹ́rìí Jìhófà (“Jehovah's Witness”)
- ẹlẹ́rìí (“witness, one who gives a testimony in court”)
- ẹlẹ́rìí-èké (“perjurer”)
- ẹ̀rí èké (“perjury”)
- ẹ̀rí-ọkàn (“conscience”)
- jẹ́rìí (“to give a testimony”)
- ohun-amúṣẹ̀rí (“exhibit”)
- ìwé-ẹ̀rí (“diploma, certificate”)