ẹrọ
Appearance
See also: Appendix:Variations of "ero"
Yoruba
[edit]Etymology
[edit]ẹ̀- (“nominalizing prefix”) + rọ (“to manufacture using metal”), literally “That which is manufactured using metal”
Pronunciation
[edit]Noun
[edit]ẹ̀rọ
Derived terms
[edit]- ẹ̀rọ abẹ̀bẹ̀ ìfẹ́atẹ́gùn (“electrical fan”)
- ẹ̀rọ agbáwòrányọ (“projector”)
- ẹ̀rọ agbéniròkè (“elevator”)
- ẹ̀rọ ajẹmọ́-omi (“hydraulic engine”)
- ẹ̀rọ amóhuntutù (“refrigerator, cooling device”)
- ẹ̀rọ amóhùnmáwòrán (“television”)
- ẹ̀rọ amúlétutù (“air conditioner”)
- ẹ̀rọ amúnimí (“ventilator”)
- ẹ̀rọ amúnáwá (“generator”)
- ẹ̀rọ amúnáwá alẹ̀fúùfù (“wind turbine”)
- ẹ̀rọ asọ̀rọ̀mágbèsì (“radio”)
- ẹ̀rọ ayàwòrán (“camera”)
- ẹ̀rọ ayárabíàṣá (“computer”)
- ẹ̀rọ ayélujára-bí-ajere (“internet”)
- ẹ̀rọ gbohùngbohùn (“speaker”)
- ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ (“cell phone, telephone”)
- ẹ̀rọ ìfọbọ́ (“dishwasher”)
- ẹ̀rọ ìfọṣọ (“washing machine”)
- ẹ̀rọ ìgbàlódé (“modern technology”)
- ẹ̀rọ ìlọǹkan (“blender”)
- ẹ̀rọ ìránṣọ (“sewing machine”)
- ẹ̀rọ ìṣirò (“calculator, mathematical computing device”)
- ẹ̀rọ ìṣàwárí (“search engine”)
- ẹ̀rọ ìtẹ̀wé (“printer”)
- ẹ̀rọ-kọ̀m̀pútà àgbáyé (“internet”)