ẹrọ gbohungbohun
Appearance
Yoruba
[edit]Etymology
[edit]Reduplication of gbohùn (“to amplify a sound/voice”).
Pronunciation
[edit]Noun
[edit]ẹ̀rọ gbohùngbohùn
- speaker, speakerphone
- microphone
- Synonym: makirofóònù
Derived terms
[edit]- gbohùngbohùn etí (“earphones”)