miringindin
Appearance
Yoruba
[edit]Etymology
[edit]Verb sense derives from ideophone sense
Pronunciation
[edit]Verb
[edit]mìrìngìndìn
- to be wonderful; to be enjoyable; to be delightful
- Ọdún á yabo, ọdún á mìrìngìndìn! ― May the year go well, may it be happy!
- 1997, “Ìjagunmólú àti Ọ̀ràn Ìbànújẹ́”, in ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower[1]:
- Bí ìwọ̀n tí ó fi ń ran àwọn ènìyàn ṣe ń lọ sílẹ̀ gan-an, ó jọ pé ọjọ́ ọ̀la yóò mìnrìngìndìn.
- As infection rates plummeted, the future looked rosy.