meriiiri
Appearance
Yoruba
[edit]Alternative forms
[edit]Etymology
[edit]From the phrase méè rí ìyí rí (“I have not seen this before”).
Pronunciation
[edit]Noun
[edit]méríìírí
- something unusual; strange
- 2022, “Ìjẹ́wọ́ Ìnàkí Shìnágawà Kan”, in Olongo Africa[1]:
- Àbí, pípín ọtí bíà àti títàkurọ̀sọ pẹ̀lú ìnàkí ṣá jẹ́ oun méríìírí.
- I mean, sharing a beer and chatting with a monkey was a pretty unusual experience in and of itself.
Derived terms
[edit]- ìwé ìtàn-àròsọ méríìírí (“genre of fantasy novel”)