From Wiktionary, the free dictionary
gbàù
- (of a sound) explosive; eruptive
- Bọ́ǹbù bú gbàù ― The bomb exploded
- Òkè Nyiragongo bú gbàù ― Nyiragongo erupted
gbáú
- (used with dá (“to break”)) snapping; breaking suddenly
- Igi dá gbáú bí igi ìṣáná ― The tree snapped like a matchstick