eleuriu
Appearance
Yoruba
[edit]Alternative forms
[edit]Pronunciation
[edit]Noun
[edit]eléuríu
- (Ekiti) a highly venomous snake
- Synonym: ejò eléuríu
- Ọmọ kọ́ bá ti ṣúlé ụba rẹ̀, ẹ gbùdọ̀ kábùjá ejò eléuríu
- A child that inherits the home of his father, must not meet the badly injured eleuriu snake
Related terms
[edit]- ọká (“gaboon viper”)
- amùrùṣoró (“boomslang”)
- àgbàádú (“spitting cobra”)
- ọ̀ọ́ta
- paramọ́lẹ̀