asiidi
Appearance
Yoruba
[edit]Etymology
[edit]Pronunciation
[edit]Noun
[edit]ásíìdì
- acid
- Synonym: omiró
- 2023, Arojinle, 0:29–0:44 from the start, in HOW NOT TO CRY WHEN CUTTING ONION[1]:
- "Propanethial-S-oxide" yìí, gáàsì ni. Lásìkò tó wá débi ojú tó bá fara kan omi díẹ̀ tó wà lórí ojú, yóò wá di ásíìdì kan tá a mọ̀ sí "tetraoxosulphate VI acid" tí wọ́n tún pè ní "sulphuric acid".
- Propanethial-S-oxide is a gas. Upon coming in contact with eye moisture it produces an acid known as tetraoxosulphate VI acid, which is also called sulphuric acid.
Derived terms
[edit]- òjò ásíìdì (“acid rain”)