From Wiktionary, the free dictionary
ọ̀yị́nyị́n
- (Ekiti) gossip, chatter
- Synonyms: ẹjọ́, ètítò
Igi ògún ẹlẹ́yọó gbà dọjà, ọ̀yị́nyị́n ì jị́n-ọn nọ̀- The large fig tree is on the path to the market, but gossiping under the tree prevented us from buying and selling
(oríkì of an Èkìtì family)