From Wiktionary, the free dictionary
From ẹni (“one; person”) + òmíì (“other”).
ẹlòmíì
- another person; someone else
- Synonym: ẹlòmíràn
Ọ̀kánjúwà kì í mu ẹ̀jẹ̀ ẹlòmíì; ẹ̀jẹ̀ ara ẹ̀ náà ní ń mu- The greedy person does not drink other people’s blood; he drinks only his own.