Ṣaina
Appearance
Yoruba
[edit]Etymology
[edit]Pronunciation
[edit]Proper noun
[edit]Ṣáínà
- China (a country in eastern Asia)
- 2008, Lérè Adèyẹmí, Kò sáyè làáfin, page 2:
- Bí wọn ti ń pè é ni Rọ́ṣíà ní wọn n bèèrè rẹ̀ ní Amẹ́ríkà, àwọn ìjọba Ṣáínà fé bá orílè̟-èdè Bóluwatife ṣe nítorí Ìwàlewà.
- (please add an English translation of this quotation)
- 2022 April 13, Eyitayọ Fauziat Oyetunji, “Shanghai pinnu láti fìyà jẹ ẹnikẹ́ni tó bá tàpá sófin ìgbélé ààrùn còrónà [Shanghai promises punishment for COVID-19 lockdown violators]”, in Ilé Akéde Nàìjíríà (Voice of Nigeria)[1], archived from the original on 16 January 2024:
- Olú-ìlú ìṣòwò orílè-èdè Ṣáínà ní Shanghai ti kìlọ̀ pé ẹnikẹ́ni tí ó bá rú àwọn òfin ìgbélé ààrùn còrónà yóò jẹyán ẹ̀ níṣu.
- The Chinese commercial capital of Shanghai warned that anyone who violates COVID-19 lockdown rules will be dealt with strictly.